ṢE TINUBU GBỌ OHUN TI FADA KUKAH SỌ FUN UN ṢA

Поделиться
HTML-код
  • Опубликовано: 18 сен 2024

Комментарии • 24

  • @MustaphaRauf
    @MustaphaRauf 4 дня назад +10

    Walahi Talahi.kosi ohun tokan. Tinubu pelu ijoba orun. Oro aiye lonle fun family tire. Awo odaju lose

  • @timothywale8055
    @timothywale8055 4 дня назад +8

    Kole gbo, boba gbo, kini gba, ki father KuKa mase fi ito enu re sofo

  • @sakenatafolabi8666
    @sakenatafolabi8666 3 дня назад

    ODODO ORO PANUBELE 👌 OPOLO YIN ONI JOBA AMIN KUNFAYAKUN 🙏❤️💜♥️

  • @PolishingYourEnglish
    @PolishingYourEnglish 4 дня назад +2

    Without any doubt, the man is WICKED!

  • @MojeedAdewole-q7l
    @MojeedAdewole-q7l 3 дня назад

    Good totuing

  • @M.AdeolaLawal
    @M.AdeolaLawal День назад

    IYAMI EKU ISE TAKUN TAKUN LATI GBA TINUBU SE IJOBA NI EJE TITA SILE KOSI IJOKAN KI EJE MATA SILE 😢😢😢😢

  • @adekunleezekiel2901
    @adekunleezekiel2901 4 дня назад +1

    OBA EGYPT NI,EYI TO PADA SEYO NI NIGERIA.

  • @labakefunmi7319
    @labakefunmi7319 4 дня назад +2

    Lara ara ilu ni won otise Gbagbo e

  • @imamabdulrasaq401
    @imamabdulrasaq401 3 дня назад

    Tinubu Kole gbo
    Awon Omo eyin re Koni je ki o gbo

  • @silifatonagun1750
    @silifatonagun1750 2 дня назад

    Kosi ina kosi omi kosi oju ona gidi, kotun si aabo ni Nigeria, haaa oma se o, Olorun a sanu fun wa

  • @silifatonagun1750
    @silifatonagun1750 2 дня назад

    Seyi ti o se ojo nlo nkan ti aba gbe ile aye se ni ama royin

  • @silifatonagun1750
    @silifatonagun1750 2 дня назад

    Awon o man wipe ebi npa eni kankan, ko si owo, kosi onje ko si ise Fulani tun pa awon agbe tan loko, awon apaniyan tun po lorisirisi, gbogbo tiwa daru patapata sugbon won tiri ikankan ro nipa iwon yen rara

  • @saheedadewale5901
    @saheedadewale5901 4 дня назад +1

    Tinubu o ni eti gbo mo rara

  • @tmmm9859
    @tmmm9859 4 дня назад

    E fe la, lowo agba yahoo

  • @OlasunkanmiFasasi
    @OlasunkanmiFasasi 3 дня назад

    Idasimeji omo orilede yi nikan lo ngbadun o

  • @Babatope-up4iu
    @Babatope-up4iu 4 дня назад

    O ti bo lowo Tinubu patapata

  • @bolajisarafadeen3279
    @bolajisarafadeen3279 4 дня назад

    Koye won ni olorun kobimo sugbon obi esan emimope gbogbo oun to won kojo loan eru olorun mabi won lere won ole latubotan rere

  • @RemilekunAdeleye-ew4dp
    @RemilekunAdeleye-ew4dp 4 дня назад

    ELOFOKAN BALE A MA GBE WA LE

  • @molad7885
    @molad7885 3 дня назад

    Tinubu ko le gbo nkankan won ti ge leti lo ati wipe koni anu mekunu loju rara